Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn ìjìyà rẹ̀, ó fi ara rẹ̀ hàn fún wọn àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀rí tí ó dájú pé òun wà láàyè. Ó fi ara hàn wọ́n fún ogójì ọjọ́, ó sì sọ̀rọ̀ nípa ìjọba Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1

Wo Ìṣe Àwọn Àpósítélì 1:3 ni o tọ