Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo gòkè lọ ní ìbámu ìfihàn, mo gbé ìyìn rere náà tí mo ń wàásù láàrin àwọn aláìkọlà kalẹ̀ níwájú wọn. Ṣùgbọ́n mo se èyí ní ìkọ̀kọ̀ fún àwọn tí ó jẹ́ olùdarí, ni ẹ̀rù pé mo ń sáré tàbí mo tí sáré ìje mi lásán.

Ka pipe ipin Gálátíà 2

Wo Gálátíà 2:2 ni o tọ