Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Gálátíà 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tí a mọ̀ pé a kò dá ẹnikẹni láre nípa iṣẹ́ òfin, bí kò ṣe nípa ìgbàgbọ́ nínú Jésù Kírísítì, àní àwa pẹ̀lú gbà Jésù Kírísítì gbọ́, kí a báa lè dá wa láre nípa ìgbàgbọ́ tí Kírísítì, kì í sì i ṣe nípa iṣẹ́ òfin: nítorí pé nípa iṣẹ́ òfin kò sí ènìyàn kan tí a ó dá láre.

Ka pipe ipin Gálátíà 2

Wo Gálátíà 2:16 ni o tọ