Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Fílípì 1:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó jẹ́ ìfojúsọ́nà àti ìrètí mi pé ojú kì yóò tì mí nínú ohunkóhun, ṣùgbọ́n èmi ó ní ìgboyà nísinsìnyìí bí ti ìgbà gbogbo pé ní yíyè, tàbí ní kíkú, a ó gbé ga lára mi.

Ka pipe ipin Fílípì 1

Wo Fílípì 1:20 ni o tọ