Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Fílípì 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òtítọ́ ni pé àwọn ẹlòmíràn tilẹ̀ ń fi ìjà àti ìlara wàásù Kírísítì, ṣùgbọ́n àwọn ẹlòmíràn sì ń fi inú rere ṣe é.

Ka pipe ipin Fílípì 1

Wo Fílípì 1:15 ni o tọ