Pọ́ọ̀lù àti Tìmótíù, àwọn ìránṣẹ́ Jésù Kírísítì,Sí gbogbo àwọn ènìyàn-mímọ́ nínú Kírísítì Jésù tí ó wà ní Fílípì, pẹ̀lú àwọn bíṣọ́ọ̀bù àti àwọn díákónì