Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 4:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Títí gbogbo wa yóò fi dé ìṣọ̀kan ìgbàgbọ́ àti ìmọ̀ Ọmọ Ọlọ́run, títí a ó fi di ọkùnrin, títí a ó fi dé ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ìwọ̀n Kírísítì.

Ka pipe ipin Éfésù 4

Wo Éfésù 4:13 ni o tọ