Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Éfésù 2:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

a sì ń gbé yín ró lórí ìpilẹ̀ àwọn àpostélì, àti àwọn wòlíì, pẹ̀lú Jésù Kírísítì fúnra rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí pàtàkì òkúta igun ilé;

Ka pipe ipin Éfésù 2

Wo Éfésù 2:20 ni o tọ