Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 9:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nítorí èyí ni ó ṣe jẹ́ alárinà májẹ̀mú tuntun pé bí ikú ti ń bẹ fún ìdáǹdè àwọn ìrékọjá ti o tí wà lábẹ́ májẹ̀mú ìṣáájú, kí àwọn tí a ti pè lè rí ilèrí ogún àìnípẹ̀kun gbà.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 9

Wo Àwọn Hébérù 9:15 ni o tọ