Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 9:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mélòómélòó ni ẹ̀jẹ̀ Kírísítì, ẹni, nípa Ẹ̀mí ayérayé, tí ó fi ara rẹ̀ rúbọ sí Ọlọ́run láìní àbàwọ́n, yóò wẹ èérí ọkàn yín nù kúrò nínú òkú iṣẹ́ láti sin Ọlọ́run alààyè?

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 9

Wo Àwọn Hébérù 9:14 ni o tọ