Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 8:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí tí o rí àbùkù lára wọn, ó wí pé,“Kíyèsí i ọjọ́ ń bọ̀, ni Olúwa wí,ti èmi o bá ilé Ísírẹ́lìàti ilé Júdà dá májẹ̀mu títún.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 8

Wo Àwọn Hébérù 8:8 ni o tọ