Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 8:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí èyí ni májẹ̀mú tí èmi yóò bá ilé Ísírẹ́lìdá lẹ̀yìn àwọn ọjọ́ wọ̀nyí, ni Olúwa wí.Èmi ó fi òfin mi sí inú wọn,èmi ó sì kọ wọ́n sí ọkàn wọn,èmi ó sì máa jẹ́ Ọlọ́run fún wọn,wọn ó sì máa jẹ́ ènìyàn fún mi.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 8

Wo Àwọn Hébérù 8:10 ni o tọ