Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 7:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nítòótọ́ àwọn tí ó jẹ́ ọmọ Léfì, tí o gba oyè àlùfáà, wọ́n ní àṣẹ láti máa gba ìdámẹ́wàá lọ́wọ́ àwọn ènìyàn gẹ́gẹ́ bí òfin, èyí yìí, lọ́wọ́ àwọn arákùnrin wọn, bí ó tilẹ̀ ti jẹ́ pé, wọn ti inú Ábúráhámù jáde.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 7

Wo Àwọn Hébérù 7:5 ni o tọ