Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 7:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé irú olórí àlùfáà bẹ́ẹ̀ ni o yẹ wá, mímọ́, àìlẹ́gàn, àìléèérí, tí a yà sọ́tọ̀ kúrò láàrin àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀, tí a sì gbéga ju àwọn ọ̀run lọ;

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 7

Wo Àwọn Hébérù 7:26 ni o tọ