Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 7:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí Melikisédékì yìí, ọba Sálẹ́mù, àlùfáà Ọlọ́run ọ̀gá ògo, ẹni tí ó pàdé Ábúráhámù bí ó ti ń padà bọ̀ láti ibi pípa àwọn ọba, tí ó sì súre fún un.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 7

Wo Àwọn Hébérù 7:1 ni o tọ