Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 6:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí tí àwa ní bi ìdákọ̀ró ọkàn fún ọkàn wa, ìrètí tí ó dájú tí ó sì dúró ṣinṣin, tí ó sì wọ inú ilé lọ lẹ̀yìn aṣọ ìkélé;

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 6

Wo Àwọn Hébérù 6:19 ni o tọ