Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 4:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí a kò ní olórí àlùfáà tí kò lè ṣàì báni kẹ́dùn nínú àìlera wa, ẹni tí a ti dánwò lọ́nà gbogbo gẹ́gẹ́ bí àwa, ṣùgbọ́n òun kò dẹ́sẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 4

Wo Àwọn Hébérù 4:15 ni o tọ