Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ǹjẹ́ bí a ti ní olórí àlùfáà ńlá kan, tí ó ti la àwọn ọ̀run kọjá lọ, Jésù ọmọ Ọlọ́run, ẹ jẹ́ kí a di ìjẹ́wọ́ wa mú ṣinṣin.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 4

Wo Àwọn Hébérù 4:14 ni o tọ