Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 4:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé ẹni tí ó ba bọ́ sínú ìsinmi rẹ̀, òun pẹ̀lú sinmi kúrò nínú iṣẹ́ tirẹ̀, gẹ́gẹ́ bí Ọlọ́run ti sinmi kúrò nínú iṣẹ́ tirẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 4

Wo Àwọn Hébérù 4:10 ni o tọ