Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 3:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ta ni ó gbọ́ tí ó sì tún ṣọ̀tẹ̀? Kì í ha ṣe gbogbo àwọn tí o jáde kúrò ní Éjíbítì ní abẹ́ àkóso Mósè?

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 3

Wo Àwọn Hébérù 3:16 ni o tọ