Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ fi ohun gbogbo sábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ̀.”Ní ti fí fi ohun gbogbo sábẹ́ rẹ̀, ṣùgbọ́n àwa kò ì tí ì rí ohun kan tí ó kù tí kò sí ní abẹ́ àkóso rẹ̀. Ṣíbẹ̀ nísinsin yìí àwa kò ì tí ì rí pé ó fi ohun gbogbo sábẹ́ ìṣàkóso rẹ̀

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 2

Wo Àwọn Hébérù 2:8 ni o tọ