Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí ni ohun náà tí ó mú wa lérò pé a lè bọ́ kúrò nínú ìjìyà bí a kò bá náání ìgbàlà ńlá yìí? Ìgbàlà tí Olúwa fúnraarẹ̀ kọ́kọ́ kéde, èyí tí a sì fi ìdí rẹ̀ múlẹ̀ fún wa láti ọwọ́ àwọn tí ó gbọ́ ọ̀rọ̀ náà lẹ́nu rẹ̀.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 2

Wo Àwọn Hébérù 2:3 ni o tọ