Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí bí ọ̀rọ̀ tí a tí ẹnu àwọn ańgẹ́lì sọ bá sì dúró ṣinṣin, àti tí olúkúlùkù ẹ̀sẹ̀ sí òfin àti àìgbọ́ràn gba ìjìyà tí ó tọ́ sí i,

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 2

Wo Àwọn Hébérù 2:2 ni o tọ