Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 13:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí nígbà tí olórí àlùfáà bá mú ẹ̀jẹ̀ àwọn ẹran wá si ibi mímọ́ gẹ́gẹ́ bí ìrúbọ ẹ̀ṣẹ̀, òkú àwọn ẹran náà ni a o sun lẹ̀yìn ibùdó.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 13

Wo Àwọn Hébérù 13:11 ni o tọ