Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 11:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣùgbọ́n làísí ìgbàgbọ́ kò ṣeéṣe láti wù ú; nítorí ẹni tí ó bá ń tọ Ọlọ́run wá kò lè sàì gbàgbọ́ pé o ń bẹ, àti pé òun ní olùṣẹ̀san fún àwọn tí o fi ara balẹ̀ wá a.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11

Wo Àwọn Hébérù 11:6 ni o tọ