Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 11:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ìgbàgbọ́ ní Ábélì rú ẹbọ sí Ọlọ́run tí ó sàn ju ti Káínì lọ, nípa èyí tí a jẹ̀rí rẹ̀ pe olódodo ni, Ọlọ́run sí ń jẹ́ri ẹ̀bùn rẹ̀: Àti nípa rẹ̀ náà, bí o ti jẹ́ pé o ti kú, síbẹ̀ o ń fọhùn.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 11

Wo Àwọn Hébérù 11:4 ni o tọ