Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ko ṣeeṣe fún ẹ̀jẹ̀ akọ màlúù àti ti ewúrẹ́ láti mú ẹ̀ṣẹ̀ kúrò.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 10

Wo Àwọn Hébérù 10:4 ni o tọ