Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Àwọn Hébérù 10:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí a ma máa kọ ìpejọpọ̀ ara wa sílẹ̀, gẹ́gẹ́ bi àṣà àwọn ẹlòmíràn; ṣùgbọ́n kí a máa gba ara ẹni niyànjú pẹ̀lúpẹ̀lú bí ẹ̀yin ti rí i pé ọjọ́ náà ń súnmọ etílé.

Ka pipe ipin Àwọn Hébérù 10

Wo Àwọn Hébérù 10:25 ni o tọ