Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

3 Jòhánù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Démétírósì ní ẹ̀rí rere lọ́dọ̀ gbogbo ènìyàn àti ní ti òtítọ́ fúnra rẹ̀ pẹ̀lú; nítòótọ́, àwa pẹ̀lú sì gba ẹ̀rí rẹ̀ jẹ́; ẹ̀yin sì mọ̀ pé, òtítọ́ ni ẹ̀rí wa.

Ka pipe ipin 3 Jòhánù 1

Wo 3 Jòhánù 1:12 ni o tọ