Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

3 Jòhánù 1:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olùfẹ́, má ṣe ṣe àfarawé ohun tí í ṣe ibi bí kò ṣe ohun tí ṣe rere. Ẹni tí ó bá ń ṣe rere ti Ọlọ́run ni; ẹni tí ó ba ń ṣe búburú kò rí Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 3 Jòhánù 1

Wo 3 Jòhánù 1:11 ni o tọ