Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tímótíù 1:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí ìdí èyí ni mo ṣe ń ran ọ létí pé kí ó máa rú ẹ̀bùn Ọlọ́run sókè èyí ti ń bẹ nínú rẹ nípa ìgbọ́wọ́lé mi.

Ka pipe ipin 2 Tímótíù 1

Wo 2 Tímótíù 1:6 ni o tọ