Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Tẹsalóníkà 3:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ẹnikẹ́ni kò bá sì pa ofin wa nínú lẹ́tà yìí mọ́, ẹ ṣààmí sí ẹni náà. Ẹ má ṣe bá a kẹ́gbẹ́ kí ojú bà á le tì í.

Ka pipe ipin 2 Tẹsalóníkà 3

Wo 2 Tẹsalóníkà 3:14 ni o tọ