Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Pétérù 1:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Símónì Pétérù, ìránṣẹ́ àti Àpósítélì Jésù Kírísítì,Sí àwọn tí ó gba irú iyebíye igbàgbọ́ kan náà pẹ̀lú wá nínú òdodo Ọlọ́run wa àti ti Jésù Kírísítì Olùgbàlà.

2. Kí oore-ọ̀fẹ́ àti àlàáfíà máa bí sí i fún yín nínú ìmọ̀ Ọlọ́run àti ti Jésù Olúwa wá.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1