Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 13:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo ti sọ fún yín ṣáájú, mo sì ń sọ fún yín tẹ́lẹ̀, bí ẹni pé mo wà pẹ̀lú yín nígbà kejì, àti bí èmi kò ti sí lọ́dọ̀ yín ní ìsinsin yìí, mo kọ̀wé sí àwọn tí ó ti ṣẹ̀ náà, àti sí gbogbo àwọn ẹlòmíran, pé bí mo bá tún padà wá, èmi kì yóò dá wọn sí.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 13

Wo 2 Kọ́ríńtì 13:2 ni o tọ