Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 12:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Òun sì wí fún mi pé, “Oore ọ̀fẹ́ mi tó fún ọ: nítorí pé a sọ agbára mi di pípé nínú àìlera.” Nítorí náà tayọ̀tayọ̀ ni èmi ó kúkú máa fí ṣògo nínú àìlera mi, kí agbára Kírísítì lè máa gbé inú mi.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 12

Wo 2 Kọ́ríńtì 12:9 ni o tọ