Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 12:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìsípayá, kí èmi má ba à gbé ara mi ga rékọjá, a sì ti fi ẹ̀gún kan sí mi lára, ìránṣẹ́ Sátanì láti pọ́n mi lójú, kí èmi má bá a gbéraga rékọjá.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 12

Wo 2 Kọ́ríńtì 12:7 ni o tọ