Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 12:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àti nígbà tí mo bá sì padà dé, kí Ọlọ́run mí má bà à rẹ̀ mí sílẹ̀ lójú yín, àti kí èmi má bà à sọkún nítorí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn tí ó tí ṣẹ̀ náà tí kò sì ronúpìwàdà ẹ̀ṣẹ̀ ìwà èérí, àgbérè, àti wọ̀bìà tí wọ́n ti hù.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 12

Wo 2 Kọ́ríńtì 12:21 ni o tọ