Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 12:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo bẹ Títù, mo sì rán arákùnrin kan pẹ̀lú rẹ̀; Títù há rẹ́ yín jẹ bí? Nípa ẹ̀mi kan náà kọ́ àwa rìn bí? Ọ̀nà kan náà kọ́ àwa tọ̀ bí?

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 12

Wo 2 Kọ́ríńtì 12:18 ni o tọ