Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 10:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé àwa kò dáṣà láti ka ara wa mọ́, tàbí láti fí ara wa wé àwọn mìíràn nínú wọn tí ń yin ara wọn; ṣùgbọ́n àwọn fúnra wọn jẹ́ aláìlóye bí wọn ti ń fí ara wọn díwọ̀n ara wọ́n, tí wọ́n sì ń fí ara wọn wé ara wọn.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 10

Wo 2 Kọ́ríńtì 10:12 ni o tọ