Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí irú ènìyàn bẹ́ẹ̀ mọ̀ pé, irú ẹni tí àwa jẹ́ nínú ọ̀rọ̀ nípa ìwé kíkọ nígbà tí àwa kò sí, irú ẹni bẹ́ẹ̀ ni àwa sì jẹ́ nínú iṣẹ́ pẹ̀lú nígbà ti àwa bá wà.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 10

Wo 2 Kọ́ríńtì 10:11 ni o tọ