Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ará, àwa kò fẹ́ kí ẹ̀yin jẹ́ òpè nípa wàhálà tí ó dé bá wa ní agbègbè Éṣíà, ní ti pé a pọ́n wa lójú gidigidi rékọjá agbára ìfaradà wa, tó bẹ́ẹ̀ tí ìrètí kò tilẹ̀ sí fún ẹ̀mí wa mọ́.

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 1

Wo 2 Kọ́ríńtì 1:8 ni o tọ