Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kọ́ríńtì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Pọ́ọ̀lù Àpósítélì Jésù Kírisítì nípa ìfẹ́ Ọlọ́run, àti Tímótíù arákùnrin wá, sí ìjọ Ọlọ́run tí ó wà ní Kọ́ríńtí pẹ̀lú gbogbo àwọn ènìyàn-mímọ́ tí ó wà ní gbogbo Ákáyà:

Ka pipe ipin 2 Kọ́ríńtì 1

Wo 2 Kọ́ríńtì 1:1 ni o tọ