Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 6:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ti ó ní ọ̀gá onígbàgbọ́, kí wọn má ṣe ṣàìbọ̀wọ̀ fún wọn nítorí tí wọn jẹ́ arákùnrin; ṣùgbọ́n kí wọn túbọ̀ máa sìn wọ́n, nítorí àwọn tí í ṣe alábàápín iṣẹ́ rere wọn jẹ́ onígbàgbọ́ àti olùfẹ́. Nǹkan wọ̀nyí ni kí ó máa kọ́ ni, kí o sì máa fi gbani níyànjú.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 6

Wo 1 Tímótíù 6:2 ni o tọ