Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 6:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí gbogbo àwọn tí i ṣe ẹrú lábẹ́ ìsìnrú máa ka àwọn olówó tí ó ni wọ́n yẹ sí ọlá gbogbo, kí a má bà á sọ̀rọ̀-òdì sí orúkọ Ọlọ́run àti ẹ̀kọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 6

Wo 1 Tímótíù 6:1 ni o tọ