Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 4:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ìwọ bá ń rán àwọn ará létí nǹkan wọ̀nyí, ìwọ ó jẹ́ iránṣẹ́ rere ti Kírísítì Jésù, tí a fi ọ̀rọ̀ ìgbàgbọ́ àti ẹ̀kọ́ rere bọ́, èyí ti ìwọ ti ń tẹ̀lé.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 4

Wo 1 Tímótíù 4:6 ni o tọ