Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tímótíù 2:13-15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

13. Nítorí Ádámù ni a kọ́ dá, lẹ́yìn náà, Éfà.

14. Ádámù kọ́ ni a tàn jẹ, ṣùgbọ́n obìnrin náà ni a tàn tí ó sì di ẹlẹ́ṣẹ̀.

15. Ṣùgbọ́n a ó gbà àwọn obìnrin là nípa ìbímọ wọn, bí wọ́n bá dúró nínú ìgbàgbọ́, ìfẹ́, àti ìwà-mímọ́ pẹ̀lú ìwà àìrékọjá.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 2