Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Tẹsalóníkà 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin ará olùfẹ́, lẹ́yìn ìgbà tí a ti kúrò lọ́dọ̀ yín fún ìgbà díẹ̀ (nínú ara, kì í ṣe ọkàn), pẹ̀lú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìtara ni àwa ṣe àníyàn tí a sì fẹ́ gidigidi láti fi rí i yín.

Ka pipe ipin 1 Tẹsalóníkà 2

Wo 1 Tẹsalóníkà 2:17 ni o tọ