Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 5:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ pẹ̀lú, ẹ̀yin ọ̀dọ́, ẹ tẹriba fún àwọn alàgbà. Àní, gbogbo yín ẹ máa tẹriba fún ara yín kí ẹ fi ìrẹ̀lẹ̀ wọ ara yin ní aṣọ: nítorí“Ọlọ́run kọ ojú ìjà sí àwọn agbéraga,ṣùgbọ́n ó ń fi oore-ọ̀fẹ́ fún àwọn onírẹ̀lẹ̀.”

Ka pipe ipin 1 Pétérù 5

Wo 1 Pétérù 5:5 ni o tọ