Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìwà yín láàrin àwọn aláìkọlà dára; pé, bí wọn ti ń sọ̀rọ̀ yín bí olùṣe búburú, nípa iṣẹ́ rere yín tí wọn ó máa kíyèsí, kí wọ́n lè máa yin Ọlọ́run lógo lọ́jọ́ ti òun ba bẹ̀ wá wò.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 2

Wo 1 Pétérù 2:12 ni o tọ