Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Pétérù 1:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwọ̀n bí ẹ̀yin ti wẹ ọkàn yin mọ́ nípa ìgbọ́ràn yín sí òtítọ́ sí ìfẹ́ ará ti kò ní ẹ̀tàn, ẹ fẹ́ ọmọnikejì yín gidigidi láti ọkàn wá.

Ka pipe ipin 1 Pétérù 1

Wo 1 Pétérù 1:22 ni o tọ